Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October 8, 2001
Ǹjẹ́ a Lè Ṣọ̀gbìn Oúnjẹ Tó Máa Pọ̀ tó?
Láìsí oúnjẹ, ebi ló máa pa ẹ̀dá èèyàn kú. Ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ sì ti ṣe bẹbẹ láti mú kó pọ̀ dáadáa. Àmọ́ ṣé ibi tó wà nínú ohun tó ṣe yìí pọ̀ ju ire tó wà níbẹ̀ lọ ni?
3 Ṣé Èèyàn Ń Pa Oúnjẹ Ara Rẹ̀ Run Ni?
4 Oríṣiríṣi Ohun Ọ̀gbìn Ṣe Kókó fún Ìwàláàyè Èèyàn
15 Adìyẹ—Ó Gbajúmọ̀, Ó sì Pọ̀ Rẹpẹtẹ
20 Ǹjẹ́ O Mọ̀?
21 Ìlú Kan ní Áfíríkà Níbi Tí Àṣà Ìlà Oòrùn àti Ìwọ̀ Oòrùn Ayé Ti Wọnú Ara Wọn
24 Orúkọ Ọlọ́run Ló Yí Ìgbésí Ayé Mi Padà!
29 Wíwo Ayé
32 A Kí I Yín Káàbọ̀ sí Àpéjọpọ̀ Àgbègbè “Àwọn Olùkọ́ni Ní Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run”!
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Dẹ́kun Dídààmú Kọjá Ààlà? 12
Àníyàn lè mú kí èèyàn máà láyọ̀ nínú ìgbésí ayé. Báwo lo ṣe lè kojú ìmọ̀lára tó ń kó ìdààmú báni yìí?
Báwo Ni Ọlọ́run Ṣe Ń Mú Nǹkan Mọ́ra Tó? 18
Kí la lè sọ pé ó mú kí Ọlọ́run ṣì fàyè gba ìwà ibi?
[Àwọn àwòrán Credit Line tó wà ní ojú ìwé 2]
ÀWÒRÁN Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Obìnrin tó wà nínú oko: Godo-Foto; àwòrán oko tó wà lójú ìwé 2: Ẹ̀ka Iṣẹ́ Ọ̀gbìn ní Orílẹ̀-Èdè Amẹ́ríkà