Oro Isaaju
Inú ayé tí onírúurú àrùn tó léwu kúnnú rẹ̀ là ń gbé. Kí la lè ṣe láti dènà àwọn àrùn yìí?
Ìwé ọgbọ́n kan tó ti wà tipẹ́tipẹ́ sọ pé: “Afọgbọ́nhùwà ni ẹni tí ó ti rí ìyọnu àjálù, tí ó sì bẹ̀rẹ̀ sí fi ara rẹ̀ pa mọ́.”—Òwe 22:3.
Ìwé ìròyìn Jí! yìí sọ àwọn nǹkan tá a lè ṣe láti dáàbò bo ara wa, ká sì tipa bẹ́ẹ̀ dènà àrùn.