Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀
KÍ LÈRÒ RẸ?
Ǹjẹ́ ìlérí yìí máa ṣẹ láéláé?
“[Ọlọ́run] yóò sì nu omijé gbogbo nù kúrò ní ojú wọn, ikú kì yóò sì sí mọ́.”—Ìṣípayá 21:3, 4.
Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ yìí sọ nípa bí Ọlọ́run ṣe máa mú ìlérí yìí ṣẹ àti àǹfààní tó máa ṣe fún ẹ.