Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé b Bó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i lórí bó o ṣe lè máa tọ́jú oúnjẹ, wo Jí! July-September 2012 ojú ìwé 3 sí 9.