Jẹ́nẹ́sísì 41:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ọ̀dọ́kùnrin kan tó jẹ́ Hébérù wà níbẹ̀ pẹ̀lú wa, ìránṣẹ́ olórí ẹ̀ṣọ́+ ni. Nígbà tí a rọ́ àlá wa fún un,+ ó túmọ̀ àlá kálukú fún un. 13 Bó ṣe túmọ̀ rẹ̀ fún wa gẹ́lẹ́ ló rí. Èmi pa dà sẹ́nu iṣẹ́ mi, àmọ́ wọ́n gbé ẹnì kejì kọ́.”+
12 Ọ̀dọ́kùnrin kan tó jẹ́ Hébérù wà níbẹ̀ pẹ̀lú wa, ìránṣẹ́ olórí ẹ̀ṣọ́+ ni. Nígbà tí a rọ́ àlá wa fún un,+ ó túmọ̀ àlá kálukú fún un. 13 Bó ṣe túmọ̀ rẹ̀ fún wa gẹ́lẹ́ ló rí. Èmi pa dà sẹ́nu iṣẹ́ mi, àmọ́ wọ́n gbé ẹnì kejì kọ́.”+