-
Jẹ́nẹ́sísì 40:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Agbọ́tí àti alásè ọba Íjíbítì tí wọ́n wà lẹ́wọ̀n lá àlá ní alẹ́ ọjọ́ kan náà, àlá tí kálukú wọn lá sì ní ìtumọ̀ tirẹ̀.