Jẹ́nẹ́sísì 37:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Wọ́n wá jókòó láti jẹun. Nígbà tí wọ́n wòkè, wọ́n rí àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì+ tó ń rìnrìn àjò tí wọ́n ń bọ̀ láti Gílíádì. Àwọn ràkúnmí wọn ru gọ́ọ̀mù lábídánọ́mù, básámù àti èèpo+ igi olóje, wọ́n ń lọ sí Íjíbítì.
25 Wọ́n wá jókòó láti jẹun. Nígbà tí wọ́n wòkè, wọ́n rí àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì+ tó ń rìnrìn àjò tí wọ́n ń bọ̀ láti Gílíádì. Àwọn ràkúnmí wọn ru gọ́ọ̀mù lábídánọ́mù, básámù àti èèpo+ igi olóje, wọ́n ń lọ sí Íjíbítì.