-
Jẹ́nẹ́sísì 41:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Àmọ́ lẹ́yìn ìyẹn, ó dájú pé ìyàn máa mú fún ọdún méje. Ó dájú pé gbogbo ohun tó pọ̀ rẹpẹtẹ nílẹ̀ Íjíbítì yóò di ohun ìgbàgbé, ìyàn yóò sì run ilẹ̀+ náà.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 47:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Nígbà tí ọdún yẹn parí, wọ́n wá bá a ní ọdún tó tẹ̀ lé e, wọ́n ń sọ fún un pé: “Ká má parọ́ fún olúwa mi, a ti kó owó wa àti ẹran ọ̀sìn wa fún olúwa mi. A ò ní nǹkan kan mọ́ tí a lè fún olúwa mi àyàfi ara wa àti ilẹ̀ wa.
-