Jẹ́nẹ́sísì 46:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Gbogbo ọmọ Jékọ́bù* tó bá a lọ sí Íjíbítì, yàtọ̀ sí ìyàwó àwọn ọmọ rẹ̀ jẹ́ mẹ́rìndínláàádọ́rin (66).+
26 Gbogbo ọmọ Jékọ́bù* tó bá a lọ sí Íjíbítì, yàtọ̀ sí ìyàwó àwọn ọmọ rẹ̀ jẹ́ mẹ́rìndínláàádọ́rin (66).+