Ẹ́kísódù 1:1-4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì tí wọ́n bá Jékọ́bù wá sí Íjíbítì nìyí, ọkùnrin kọ̀ọ̀kan tó mú agbo ilé rẹ̀ wá:+ 2 Rúbẹ́nì, Síméónì, Léfì àti Júdà;+ 3 Ísákà, Sébúlúnì àti Bẹ́ńjámínì; 4 Dánì àti Náfútálì; Gádì àti Áṣérì.+
1 Orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì tí wọ́n bá Jékọ́bù wá sí Íjíbítì nìyí, ọkùnrin kọ̀ọ̀kan tó mú agbo ilé rẹ̀ wá:+ 2 Rúbẹ́nì, Síméónì, Léfì àti Júdà;+ 3 Ísákà, Sébúlúnì àti Bẹ́ńjámínì; 4 Dánì àti Náfútálì; Gádì àti Áṣérì.+