Jẹ́nẹ́sísì 41:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Jósẹ́fù+ ti bí ọmọkùnrin méjì kí ìyàn tó bẹ̀rẹ̀ sí í mú. Ásénátì ọmọ Pọ́tíférà àlùfáà Ónì* ló bí àwọn ọmọ náà fún un.
50 Jósẹ́fù+ ti bí ọmọkùnrin méjì kí ìyàn tó bẹ̀rẹ̀ sí í mú. Ásénátì ọmọ Pọ́tíférà àlùfáà Ónì* ló bí àwọn ọmọ náà fún un.