-
Jẹ́nẹ́sísì 25:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ọjọ́ ayé Ábúráhámù jẹ́ ọdún márùndínlọ́gọ́sàn-án (175).
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 35:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Ọjọ́ ayé Ísákì sì jẹ́ ọgọ́sàn-án (180) ọdún.+
-