-
Jẹ́nẹ́sísì 7:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Jèhófà wá sọ fún Nóà pé: “Wọ inú áàkì, ìwọ àti gbogbo ìdílé rẹ, torí ìwọ ni mo rí pé ó jẹ́ olódodo níwájú mi nínú ìran yìí.+