Diutarónómì 33:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ó sọ nípa Gádì pé:+ “Ìbùkún ni fún ẹni tó ń mú kí àwọn ààlà Gádì+ fẹ̀ sí i. Ó dùbúlẹ̀ síbẹ̀ bíi kìnnìún,Tó múra tán láti fa apá ya, àní àtàrí.
20 Ó sọ nípa Gádì pé:+ “Ìbùkún ni fún ẹni tó ń mú kí àwọn ààlà Gádì+ fẹ̀ sí i. Ó dùbúlẹ̀ síbẹ̀ bíi kìnnìún,Tó múra tán láti fa apá ya, àní àtàrí.