Ẹ́sítà 2:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ọkùnrin Júù kan wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* Módékáì+ lorúkọ rẹ̀, ó jẹ́ ọmọ Jáírì, ọmọ Ṣíméì, ọmọ Kíṣì, ọmọ Bẹ́ńjámínì,+ Ẹ́sítà 8:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí náà, Ọba Ahasuérúsì sọ fún Ẹ́sítà Ayaba àti Módékáì tó jẹ́ Júù pé: “Ẹ wò ó! Mo ti fún Ẹ́sítà ní ilé Hámánì,+ mo sì ti ní kí wọ́n gbé e kọ́ sórí òpó igi,+ nítorí ète tó pa láti gbéjà ko* àwọn Júù.
5 Ọkùnrin Júù kan wà ní Ṣúṣánì*+ ilé ńlá,* Módékáì+ lorúkọ rẹ̀, ó jẹ́ ọmọ Jáírì, ọmọ Ṣíméì, ọmọ Kíṣì, ọmọ Bẹ́ńjámínì,+
7 Nítorí náà, Ọba Ahasuérúsì sọ fún Ẹ́sítà Ayaba àti Módékáì tó jẹ́ Júù pé: “Ẹ wò ó! Mo ti fún Ẹ́sítà ní ilé Hámánì,+ mo sì ti ní kí wọ́n gbé e kọ́ sórí òpó igi,+ nítorí ète tó pa láti gbéjà ko* àwọn Júù.