-
Jẹ́nẹ́sísì 23:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Lẹ́yìn náà, Ábúráhámù sin Sérà ìyàwó rẹ̀ sínú ihò tó wà ní Mákípẹ́là níwájú Mámúrè, ìyẹn ní Hébúrónì, ní ilẹ̀ Kénáánì.