-
Jẹ́nẹ́sísì 23:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Nípa báyìí, ilẹ̀ Éfúrónì tó wà ní Mákípẹ́là níwájú Mámúrè, ilẹ̀ náà àti ihò tó wà níbẹ̀ àti gbogbo igi tó wà lórí ilẹ̀ náà wá di 18 ohun ìní Ábúráhámù, èyí tó rà níṣojú àwọn ọmọ Hétì àti gbogbo àwọn tó ń gba ẹnubodè ìlú rẹ̀ wọlé.
-