Jẹ́nẹ́sísì 7:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ní ọjọ́ yẹn gan-an, Nóà wọ inú áàkì pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀, Ṣémù, Hámù àti Jáfẹ́tì,+ pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ àti ìyàwó àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta.+
13 Ní ọjọ́ yẹn gan-an, Nóà wọ inú áàkì pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀, Ṣémù, Hámù àti Jáfẹ́tì,+ pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ àti ìyàwó àwọn ọmọ rẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta.+