Jẹ́nẹ́sísì 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kí o ṣe fèrèsé* tí ìmọ́lẹ̀ á máa gbà wọ* inú áàkì náà, kó jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan láti òkè. Kí o ṣe ẹnu ọ̀nà áàkì náà sí ẹ̀gbẹ́ rẹ̀,+ kí o sì jẹ́ kó ní àjà kìíní, àjà kejì àti àjà kẹta.
16 Kí o ṣe fèrèsé* tí ìmọ́lẹ̀ á máa gbà wọ* inú áàkì náà, kó jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ kan láti òkè. Kí o ṣe ẹnu ọ̀nà áàkì náà sí ẹ̀gbẹ́ rẹ̀,+ kí o sì jẹ́ kó ní àjà kìíní, àjà kejì àti àjà kẹta.