Jẹ́nẹ́sísì 9:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ọlọ́run sì fi kún un pé: “Àmì májẹ̀mú tí mò ń bá ẹ̀yin àti gbogbo ohun alààyè* tó wà pẹ̀lú yín dá nìyí, jálẹ̀ gbogbo ìran tó ń bọ̀ lọ́jọ́ iwájú. 13 Mo fi òṣùmàrè mi sí ojú ọ̀run, ó sì máa jẹ́ àmì májẹ̀mú tó wà láàárín èmi àti ayé.
12 Ọlọ́run sì fi kún un pé: “Àmì májẹ̀mú tí mò ń bá ẹ̀yin àti gbogbo ohun alààyè* tó wà pẹ̀lú yín dá nìyí, jálẹ̀ gbogbo ìran tó ń bọ̀ lọ́jọ́ iwájú. 13 Mo fi òṣùmàrè mi sí ojú ọ̀run, ó sì máa jẹ́ àmì májẹ̀mú tó wà láàárín èmi àti ayé.