Jẹ́nẹ́sísì 9:18, 19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Àwọn ọmọ Nóà tó jáde nínú áàkì ni Ṣémù, Hámù àti Jáfẹ́tì.+ Nígbà tó yá, Hámù bí Kénáánì.+ 19 Àwọn mẹ́ta yìí ni ọmọ Nóà, àwọn ló sì bí gbogbo èèyàn tó wà ní ayé, tí wọ́n sì tàn káàkiri.+
18 Àwọn ọmọ Nóà tó jáde nínú áàkì ni Ṣémù, Hámù àti Jáfẹ́tì.+ Nígbà tó yá, Hámù bí Kénáánì.+ 19 Àwọn mẹ́ta yìí ni ọmọ Nóà, àwọn ló sì bí gbogbo èèyàn tó wà ní ayé, tí wọ́n sì tàn káàkiri.+