7 Jèhófà Ọlọ́run ọ̀run, ẹni tó mú mi kúrò ní ilé bàbá mi àti ilẹ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí+ mi, ẹni tó bá mi sọ̀rọ̀, tó sì búra fún mi+ pé: ‘Ọmọ+ rẹ ni èmi yóò fún ní ilẹ̀ yìí,’+ yóò rán áńgẹ́lì rẹ̀ lọ ṣáájú rẹ,+ ó sì dájú pé wàá mú ìyàwó wá fún ọmọ mi láti ibẹ̀.+