Jẹ́nẹ́sísì 10:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó di ọdẹ alágbára tó ń ta ko Jèhófà. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi máa ń sọ pé: “Bíi Nímírọ́dù ọdẹ alágbára tó ta ko Jèhófà.” 10 Ibi tí ìjọba rẹ̀ ti bẹ̀rẹ̀ ni* Bábélì,+ Érékì,+ Ákádì àti Kálínè, ní ilẹ̀ Ṣínárì.+
9 Ó di ọdẹ alágbára tó ń ta ko Jèhófà. Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi máa ń sọ pé: “Bíi Nímírọ́dù ọdẹ alágbára tó ta ko Jèhófà.” 10 Ibi tí ìjọba rẹ̀ ti bẹ̀rẹ̀ ni* Bábélì,+ Érékì,+ Ákádì àti Kálínè, ní ilẹ̀ Ṣínárì.+