Gálátíà 4:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Hágárì dúró fún Sínáì,+ òkè kan ní Arébíà, ó sì ṣe rẹ́gí pẹ̀lú Jerúsálẹ́mù ti òní, torí ó ń ṣẹrú pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀.
25 Hágárì dúró fún Sínáì,+ òkè kan ní Arébíà, ó sì ṣe rẹ́gí pẹ̀lú Jerúsálẹ́mù ti òní, torí ó ń ṣẹrú pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀.