Jẹ́nẹ́sísì 21:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ábúráhámù sì dádọ̀dọ́* Ísákì ọmọ rẹ̀ nígbà tó pé ọmọ ọjọ́ mẹ́jọ, bí Ọlọ́run ṣe pa á láṣẹ fún un.+ Róòmù 2:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Àmọ́ ẹni tó jẹ́ Júù ní inú ni Júù,+ ìdádọ̀dọ́* rẹ̀ sì jẹ́ ti ọkàn+ nípa ẹ̀mí, kì í ṣe nípa àkọsílẹ̀ òfin.+ Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ìyìn ẹni yẹn ti wá, kì í ṣe láti ọ̀dọ̀ èèyàn.+
29 Àmọ́ ẹni tó jẹ́ Júù ní inú ni Júù,+ ìdádọ̀dọ́* rẹ̀ sì jẹ́ ti ọkàn+ nípa ẹ̀mí, kì í ṣe nípa àkọsílẹ̀ òfin.+ Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni ìyìn ẹni yẹn ti wá, kì í ṣe láti ọ̀dọ̀ èèyàn.+