Hébérù 11:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ìgbàgbọ́ mú kí Sérà náà gba agbára láti lóyún ọmọ,* kódà nígbà tí ọjọ́ orí rẹ̀ ti kọjá ti ẹni tó lè bímọ,+ torí ó ka Ẹni tó ṣe ìlérí náà sí olóòótọ́.* 1 Pétérù 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 bí Sérà ṣe ń ṣègbọràn sí Ábúráhámù, tó ń pè é ní olúwa.+ Ẹ sì ti di ọmọ rẹ̀, tí ẹ bá ń ṣe ohun tó dáa, tí ẹ ò sì bẹ̀rù.+
11 Ìgbàgbọ́ mú kí Sérà náà gba agbára láti lóyún ọmọ,* kódà nígbà tí ọjọ́ orí rẹ̀ ti kọjá ti ẹni tó lè bímọ,+ torí ó ka Ẹni tó ṣe ìlérí náà sí olóòótọ́.*
6 bí Sérà ṣe ń ṣègbọràn sí Ábúráhámù, tó ń pè é ní olúwa.+ Ẹ sì ti di ọmọ rẹ̀, tí ẹ bá ń ṣe ohun tó dáa, tí ẹ ò sì bẹ̀rù.+