-
Jẹ́nẹ́sísì 24:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 ó nì: “Ìyìn yẹ Jèhófà, Ọlọ́run ọ̀gá mi Ábúráhámù, torí ó ṣì nífẹ̀ẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ọ̀gá mi, ó sì jẹ́ olóòótọ́ sí i. Jèhófà ti darí mi wá sí ilé àwọn mọ̀lẹ́bí ọ̀gá mi.”
-