-
Jẹ́nẹ́sísì 27:29, 30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Kí àwọn èèyàn máa sìn ọ́, kí àwọn orílẹ̀-èdè sì máa tẹrí ba fún ọ. Kí o di ọ̀gá lórí àwọn arákùnrin rẹ, kí àwọn ọmọ ìyá rẹ sì máa tẹrí ba fún ọ.+ Kí ègún wà lórí ẹnikẹ́ni tó bá gégùn-ún fún ọ, kí ìbùkún sì wà lórí ẹnikẹ́ni tó bá ń súre fún ọ.”+
30 Bí Ísákì ṣe súre fún Jékọ́bù tán, tí Jékọ́bù sì kúrò lọ́dọ̀ Ísákì bàbá rẹ̀ ni Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ dé láti oko ọdẹ.+
-