-
Jẹ́nẹ́sísì 27:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Bí Ísákì ṣe súre fún Jékọ́bù tán, tí Jékọ́bù sì kúrò lọ́dọ̀ Ísákì bàbá rẹ̀ ni Ísọ̀ ẹ̀gbọ́n rẹ̀ dé láti oko ọdẹ.+