-
Jẹ́nẹ́sísì 35:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Jékọ́bù sì gbé òpó kan dúró níbi tí Ọlọ́run ti bá a sọ̀rọ̀, òpó òkúta ni, ó sì da ọrẹ ohun mímu àti òróró sórí rẹ̀.+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 37:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Jékọ́bù ń gbé ilẹ̀ Kénáánì nìṣó, ibi tí bàbá rẹ̀ gbé bí àjèjì.+
-