34 Nígbà tí Ísọ̀ pé ẹni ogójì (40) ọdún, ó fi Júdítì ọmọ Béérì, ọmọ Hétì ṣe aya àti Básémátì ọmọ Ẹ́lónì, ọmọ Hétì.+35 Wọ́n ba Ísákì àti Rèbékà+ nínú jẹ́* gidigidi.
46 Lẹ́yìn ìyẹn, Rèbékà ń tẹnu mọ́ ọn fún Ísákì pé: “Àwọn ọmọbìnrin Hétì+ ti fayé sú mi. Bí Jékọ́bù bá lọ fẹ́ ìyàwó nínú àwọn ọmọ Hétì, irú àwọn ọmọbìnrin ilẹ̀ yìí, kí làǹfààní pé mo wà láàyè?”+