-
Jẹ́nẹ́sísì 26:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Nígbà tí Ísọ̀ pé ẹni ogójì (40) ọdún, ó fi Júdítì ọmọ Béérì, ọmọ Hétì ṣe aya àti Básémátì ọmọ Ẹ́lónì, ọmọ Hétì.+