Ẹ́kísódù 38:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Gbogbo wúrà tí wọ́n lò fún gbogbo iṣẹ́ ibi mímọ́ náà dọ́gba pẹ̀lú iye wúrà ọrẹ fífì,+ ó jẹ́ tálẹ́ńtì* mọ́kàndínlọ́gbọ̀n (29) àti ọgọ́rùn-ún méje ó lé ọgbọ̀n (730) ṣékélì,* ìwọ̀n ṣékélì ibi mímọ́.*
24 Gbogbo wúrà tí wọ́n lò fún gbogbo iṣẹ́ ibi mímọ́ náà dọ́gba pẹ̀lú iye wúrà ọrẹ fífì,+ ó jẹ́ tálẹ́ńtì* mọ́kàndínlọ́gbọ̀n (29) àti ọgọ́rùn-ún méje ó lé ọgbọ̀n (730) ṣékélì,* ìwọ̀n ṣékélì ibi mímọ́.*