-
Ẹ́kísódù 28:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Kí o fi okùn aláwọ̀ búlúù di aṣọ ìgbàyà náà mú, kí o fi okùn náà so àwọn òrùka aṣọ ìgbàyà náà mọ́ àwọn òrùka éfódì. Èyí máa mú kí aṣọ ìgbàyà náà dúró lórí éfódì náà, lókè àmùrè* éfódì tí wọ́n hun.
-
-
Ẹ́kísódù 39:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Wọ́n wá ṣe ẹ̀wọ̀n tó lọ́ pọ̀ sára aṣọ ìgbàyà náà, bí okùn tí wọ́n fi ògidì wúrà ṣe.+
-
-
Ẹ́kísódù 39:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Níkẹyìn, wọ́n fi okùn aláwọ̀ búlúù so àwọn òrùka aṣọ ìgbàyà náà mọ́ àwọn òrùka éfódì náà, kí aṣọ ìgbàyà náà lè dúró lórí éfódì náà, lókè àmùrè* tí wọ́n hun, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.
-