-
Ẹ́kísódù 30:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Igi bọn-ọ̀n-ní ni kí o fi ṣe àwọn ọ̀pá náà, kí o sì fi wúrà bò wọ́n.
-
-
Ẹ́kísódù 36:36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
36 Lẹ́yìn náà, ó fi igi bọn-ọ̀n-ní ṣe òpó mẹ́rin fún un, ó sì fi wúrà bò wọ́n, pẹ̀lú àwọn ìkọ́ tó fi wúrà ṣe, ó sì fi fàdákà rọ ìtẹ́lẹ̀ mẹ́rin tó ní ihò fún wọn.
-