-
2 Àwọn Ọba 18:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Rábúṣákè bá dìde, ó gbé ohùn rẹ̀ sókè, ó sì fi èdè àwọn Júù sọ̀rọ̀, ó ní: “Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ ọba ńlá, ọba Ásíríà.+
-
-
2 Àwọn Ọba 18:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Èwo nínú gbogbo ọlọ́run àwọn ilẹ̀ náà ló ti gba ilẹ̀ wọn kúrò lọ́wọ́ mi, tí Jèhófà yóò fi gba Jerúsálẹ́mù kúrò lọ́wọ́ mi?”’”+
-