18 “Ó dájú pé wọ́n á fetí sí ohùn rẹ,+ ìwọ àti àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì yóò lọ bá ọba Íjíbítì, ẹ ó sì sọ fún un pé, ‘Jèhófà Ọlọ́run àwọn Hébérù+ ti bá wa sọ̀rọ̀. Torí náà, jọ̀ọ́, jẹ́ ká rin ìrìn àjò ọjọ́ mẹ́ta lọ sí aginjù, ká lè rúbọ sí Jèhófà Ọlọ́run wa.’+