36 “Kí o fi ògidì wúrà ṣe irin pẹlẹbẹ tó ń dán, kí o sì fín ọ̀rọ̀ yìí sára rẹ̀ bí ẹni fín èdìdì, pé: ‘Ìjẹ́mímọ́ jẹ́ ti Jèhófà.’+37 Kí o fi okùn aláwọ̀ búlúù dè é mọ́ ara láwàní;+ kó máa wà níwájú láwàní náà.
9 Lẹ́yìn náà, ó wé láwàní+ sí i lórí, ó sì fi irin wúrà pẹlẹbẹ tó ń dán tó jẹ́ àmì mímọ́ ti ìyàsímímọ́*+ sí iwájú láwàní náà, bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ fún Mósè.