Ẹ́kísódù 35:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “‘Kí gbogbo àwọn tó mọṣẹ́*+ láàárín yín wá ṣe gbogbo ohun tí Jèhófà pa láṣẹ, Ẹ́kísódù 36:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 “Kí Bẹ́sálẹ́lì ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Òhólíábù àti gbogbo ọkùnrin tó mọṣẹ́* tí Jèhófà ti fún ní ọgbọ́n àti òye kí wọ́n lè mọ bí wọ́n á ṣe ṣe gbogbo iṣẹ́ ìsìn mímọ́ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ.”+
36 “Kí Bẹ́sálẹ́lì ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Òhólíábù àti gbogbo ọkùnrin tó mọṣẹ́* tí Jèhófà ti fún ní ọgbọ́n àti òye kí wọ́n lè mọ bí wọ́n á ṣe ṣe gbogbo iṣẹ́ ìsìn mímọ́ bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ.”+