-
Ẹ́kísódù 26:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 “Kí o gbé tábìlì sí ìta aṣọ ìdábùú náà, kí ọ̀pá fìtílà+ náà dojú kọ tábìlì náà ní apá gúúsù àgọ́ ìjọsìn; kí o sì gbé tábìlì náà sí apá àríwá.
-