Ẹ́kísódù 25:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Kí o sì máa gbé búrẹ́dì àfihàn sórí tábìlì níwájú mi ní gbogbo ìgbà.+ Mátíù 12:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Bó ṣe wọ ilé Ọlọ́run, tí wọ́n sì jẹ àwọn búrẹ́dì tí wọ́n ń gbé síwájú,*+ èyí tí kò bófin mu fún òun àti àwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀ láti jẹ, àfi àwọn àlùfáà nìkan?+
4 Bó ṣe wọ ilé Ọlọ́run, tí wọ́n sì jẹ àwọn búrẹ́dì tí wọ́n ń gbé síwájú,*+ èyí tí kò bófin mu fún òun àti àwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀ láti jẹ, àfi àwọn àlùfáà nìkan?+