-
Ẹ́kísódù 14:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé kí wọ́n ṣẹ́rí pa dà, kí wọ́n sì pàgọ́ síwájú Píháhírótì, láàárín Mígídólì àti òkun, níbi tí wọ́n á ti máa rí Baali-séfónì lọ́ọ̀ọ́kán.+ Kí ẹ pàgọ́ síbi tó dojú kọ ọ́ lẹ́gbẹ̀ẹ́ òkun. 3 Fáráò yóò wá sọ nípa àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé, ‘Ṣe ni wọ́n ń rìn gbéregbère káàkiri ilẹ̀. Wọ́n ti há sí aginjù.’
-
-
Nọ́ńbà 33:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní Rámésésì, wọ́n sì pàgọ́ sí Súkótù.+
-