-
Diutarónómì 20:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 torí Jèhófà Ọlọ́run yín ń bá yín lọ kó lè jà fún yín láti ṣẹ́gun àwọn ọ̀tá yín, kó sì gbà yín là.’+
-
-
2 Kíróníkà 20:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 Ẹ̀rù Ọlọ́run ba gbogbo ìjọba àwọn orílẹ̀-èdè nígbà tí wọ́n gbọ́ pé Jèhófà ti bá àwọn ọ̀tá Ísírẹ́lì jà.+
-