Ẹ́kísódù 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nígbà yẹn, Mósè àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọ orin yìí sí Jèhófà:+ “Jẹ́ kí n kọrin sí Jèhófà, torí ó ti di ẹni àgbéga.+ Ó taari ẹṣin àti ẹni tó gùn ún sínú òkun.+ Ẹ́kísódù 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó ti ju àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin Fáráò àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sínú òkun,+ Àwọn tó dára jù nínú àwọn jagunjagun rẹ̀ sì ti rì sínú Òkun Pupa.+
15 Nígbà yẹn, Mósè àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọ orin yìí sí Jèhófà:+ “Jẹ́ kí n kọrin sí Jèhófà, torí ó ti di ẹni àgbéga.+ Ó taari ẹṣin àti ẹni tó gùn ún sínú òkun.+
4 Ó ti ju àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin Fáráò àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sínú òkun,+ Àwọn tó dára jù nínú àwọn jagunjagun rẹ̀ sì ti rì sínú Òkun Pupa.+