8 Nítorí náà, ó dìde, ó jẹ, ó mu, oúnjẹ náà sì fún un lágbára láti rin ìrìn ogójì (40) ọ̀sán àti ogójì (40) òru títí ó fi dé Hórébù, òkè Ọlọ́run tòótọ́.+
9 Ó wọnú ihò+ kan níbẹ̀, ó sì sùn mọ́jú; sì wò ó! Jèhófà bá a sọ̀rọ̀, ó sọ fún un pé: “Kí lò ń ṣe níbí, Èlíjà?”