Nọ́ńbà 14:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 “Ìgbà wo ni àwọn èèyàn burúkú yìí máa tó jáwọ́ kíkùn sí mi?+ Mo ti gbọ́ ohun táwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń sọ nígbà tí wọ́n ń kùn sí mi.+
27 “Ìgbà wo ni àwọn èèyàn burúkú yìí máa tó jáwọ́ kíkùn sí mi?+ Mo ti gbọ́ ohun táwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń sọ nígbà tí wọ́n ń kùn sí mi.+