Nọ́ńbà 15:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 “‘Ṣùgbọ́n ẹni* tó bá mọ̀ọ́mọ̀ ṣe+ ohun kan ń kó ẹ̀gàn bá Jèhófà, ì báà jẹ́ ọmọ ìbílẹ̀ tàbí àjèjì, torí náà, ṣe ni kí ẹ pa á, kí ẹ lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.
30 “‘Ṣùgbọ́n ẹni* tó bá mọ̀ọ́mọ̀ ṣe+ ohun kan ń kó ẹ̀gàn bá Jèhófà, ì báà jẹ́ ọmọ ìbílẹ̀ tàbí àjèjì, torí náà, ṣe ni kí ẹ pa á, kí ẹ lè mú un kúrò láàárín àwọn èèyàn rẹ̀.