-
Diutarónómì 19:17Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 kí àwọn méjèèjì tó ń bára wọn fa ọ̀rọ̀ wá dúró níwájú Jèhófà, níwájú àwọn àlùfáà àti àwọn adájọ́ tí wọ́n á máa dájọ́ nígbà yẹn.+
-