-
Ẹ́kísódù 19:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Jèhófà sọ fún Mósè pé: “Wò ó! Màá wá sọ́dọ̀ rẹ nínú ìkùukùu* tó ṣú dùdù, kí àwọn èèyàn náà lè gbọ́ nígbà tí mo bá ń bá ọ sọ̀rọ̀, kí wọ́n sì lè tipa bẹ́ẹ̀ máa gba ìwọ náà gbọ́.” Lẹ́yìn náà, Mósè mú èsì àwọn èèyàn náà tọ Jèhófà lọ.
-