Ẹ́kísódù 38:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Bàbà ni wọ́n fi ṣe ìtẹ́lẹ̀ oníhò àwọn òpó náà, fàdákà ni wọ́n fi ṣe àwọn ìkọ́ wọn àti àwọn ohun tó so wọ́n pọ̀,* wọ́n fi fàdákà bo orí àwọn òpó náà, fàdákà sì ni wọ́n fi ṣe àwọn ohun tí wọ́n fi ń de nǹkan pọ̀ mọ́ gbogbo òpó inú àgbàlá náà.+
17 Bàbà ni wọ́n fi ṣe ìtẹ́lẹ̀ oníhò àwọn òpó náà, fàdákà ni wọ́n fi ṣe àwọn ìkọ́ wọn àti àwọn ohun tó so wọ́n pọ̀,* wọ́n fi fàdákà bo orí àwọn òpó náà, fàdákà sì ni wọ́n fi ṣe àwọn ohun tí wọ́n fi ń de nǹkan pọ̀ mọ́ gbogbo òpó inú àgbàlá náà.+